Leyin to de lati ibi isinku ni pasito yii naa ku - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, July 3, 2023

Leyin to de lati ibi isinku ni pasito yii naa ku


Inu ibanuje lawon molebi ati Omo ijo pasito Mike wa bayii pelu bo se fo sanle to si ku lose to koja nipinle Akwa Ibom
Ko pe to de lati ibi isinku Omo ijo e to n je Joy,loun naa ku sugbon a gbo pe pasito naa ti n saisan tele

No comments:

Post a Comment

Pages