Api baide tu yuuu mama oloriire - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, July 31, 2023

Api baide tu yuuu mama oloriire

Ojo satide to koja ni mama Bimbo Akisanya to je gbajumo oseretiata obinrin se ojo ibi fun iya re nigboro ilu Eko,ese ko gba ero rara lojo naa,opo awon borokini ati awon eeyan Pataki lawujo ni won wa ba mama daadaa yii sajoyo ojo ibi odun ogorin in , adura ti wa ni pe emi yin a sopo odun laye beeni onje Omo atubo jina fun yin je,api baide tu yuuu ma

No comments:

Post a Comment

Pages