Gbajumo olorin juju nni iyen Boye' Best lo dalubole lojo ti mama Bimbo Akisanya sayeye ogorin in odun loke eepe,gongo so lojo naa nipinle Eko nitori opo awon ololufe Bimbo ati mama ni won peju sibi ayeye ojo ibi mama oloriire yii,mama Abosede Akisanya emi yin a sopo odun laye,api baide tu yuuu ma
Monday, July 31, 2023
Ope o,mama Bimbo Akisanya Arewa oseretiata obinrin pe Ogorin in odun laye
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment