Saheed Osupa ati egbon e,Lateef Okunola se bebe ni Orile ede Canada - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, July 31, 2023

Saheed Osupa ati egbon e,Lateef Okunola se bebe ni Orile ede Canada

lattylibra ileese to n gbe Awon olorin Fuji jade,to tun je egbon oba Orin,Alaaji Saheed Osupa se bebe lose to koja yii ni Orile ede Canada
Ogbontarigi puromota nni iyen Libra Okunola lo gbe aburo e,Saheed Osupa wo orile ede naa,ti Inu gbogbo awon ololufe Orin Fuji si dun fun igbese ti Omo baba kan na yii gbe.

No comments:

Post a Comment

Pages