ileese Lattylibra international promotion ati oba Orin iyen Alaaji Saheed Babatunde Osupa se bebe lopin ose to koja yii ni Orile ede Canada,tegbon taburo yii ni won gbe faaji repete wo orile ede naa tawon ololufe Fuji ati Osupa si forin re daraya lopin ose to koja,ka ma tan ara wa je,awon Omo Okunola migboro Montreal ni Canada titi lose to koja
Monday, July 31, 2023
Omo baba Kanna an se bebe lorile ede Canada
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment