Odu ni Ogbeni Oguntoyinbo je ninu egbe oselu Nnpp nipinle Ogun,oun ni oludije sipo Gomina nipinle naa ninu eto idibo to koja.Ose to koja ni egbe Akoroyin l'ede Yoruba sabewo si Ogbeni to tun je oludasile ileese Coco Samba iyen ileese Apoogun,o ti wa je ko di Mimo lojo naa pe,oun si maa dupo Aare orile ede yii nitori asoju awon Odo ti won je ojo ojo ola Orile ede Naijiria loun
Ogbeni yii tun wa Fi aidunnu re han Lori iwa ti Alaga egbe oselu Nnpp nipinle Ogun iyen Oloye Oginni Wu si I lasiko idibo sipo Gomina ipinle naa pelu bo se kede pe,egbe oselu Nnpp ti darapo mo egbe oselu PDP Lai so fun oun rara
O so pe,odale ati onijekuje ni Ogbeni Oginni pelu igbese alabosi to gbe nigba naa ti oun si kabamo pe,ojelu loun ba sise.Oludasile ileese Coco Samba tun menu ba Oro awon onifuji nitori onisowo katakara Orin Fuji ni pelu,o so pe Olori ebi Olufimo iyen Alaaji Saheed Osupa ni aayo oun laarin awon onifuji,oun si ti n sise lori bawon mejeeji yoo se sise papo loke Okun laipe

No comments:
Post a Comment