Orin Wasiu Ayinde ni mo maa n ji ko lasiko ti mo bere si I ni korin fuji-Olunla Aroworeyin - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, July 14, 2023

Orin Wasiu Ayinde ni mo maa n ji ko lasiko ti mo bere si I ni korin fuji-Olunla Aroworeyin


Aare Akanni Aroworeyin Adeshina,eniti awon ololufe e tun mo si Scopido Ogolorinwa ti so jade pe,eeyan gidi ni Alaaji Wasiu Ayinde to tun je Mayegun Ile Yoruba
Aare Akanni soro yii lasiko ti egbe Akoroyin l'ede Yoruba sabewo si I nile re laipe,ti Ogbeni to sese de lati Orile ede America naa si ti so pe, Oluaye Fuji gan an ni awokose oun nidi ise Fuji

O wa tun dupe lowo egbe onifuji,bee lo tun sedaro oloogbe 'Baby Barrister pelu, Ogolorinwa ti wa so pe,egbon gidi ni Oloriomooba Ile Ijebu lasiko yii iyen Alaaji Wasiu Ayinde je si oun,bee ni oun ko le ko iyan re kere rara 

No comments:

Post a Comment

Pages