Ileese Adrons ti n ta Ile nipinle plateau - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, July 14, 2023

Ileese Adrons ti n ta Ile nipinle plateau


Fun gbogbo eyin ololufe ati onibara ileese Adrons iyen ileese to se e fowo soya lasiko yii nipa karakata Ile ati Ile gbigbe,a layo lati so fun un yin pe,ileese Adrons ti ni awon Ile ni Jos pelu owo ti ko gara rara
Ti e ba Fe se adugbo ti yinyin tutu ti maa n jabo bii enipe e wa nilu oyinbo,ati ibi to tutu bii ilu oba ,e tete kan sileese Adrons,won yoo ba yin wa Ile sawon adugbo to dara nipinle Plateau ati agbegbe re

No comments:

Post a Comment

Pages