Asiri tu,Wolii Olagoroye Faleyinmu ti so asiri to wa nidi aisan Gomina Akeredolu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, July 14, 2023

Asiri tu,Wolii Olagoroye Faleyinmu ti so asiri to wa nidi aisan Gomina Akeredolu

Ariran agbaye nni iyen Wolii Olagoroye Faleyinmu ti so pe,aisan to n se Gomina ipinle Ondo iyen Arakunrin Akeredolu ki n se aisan lasan,o so pe idasile egbe Iko Amotekun wa lara ohun to fa aisan naa ati pe Arakunrin tun toju bo iyansipo oba ilu Owo nipinle Ondo ti Inu opo awon olugbe ipinle naa ko SI dun si iwa yii
Wolii Faleyinmu so pe,awon Aje ti pin eran ara Akeredolu sugbon pelu adura o seese ki Olorun Fi odun die Kun odun re Lori Ile aye
Ariran agbaye tun soro nipa Aare Tuntun ti a sese fibo gbe wole pe,ko sora ko SI tun Kun fun adura ki emi re le gun Lori ipo Aare to wa naa,sugbon OSU mefa Akoko re yoo mu inira die wa fawon olugbe orile ede yii.
Sa o, Ariran Faleyinmu ti so pe,ki Arakunrin Akeredolu lo tera mo adura beeni ki Aare Tinubu naa mo pe,owo Olorun ni aabo wa lasiko yii,nitori aarin Ota ni Aare Tinubu wa sugbon pelu adura ohun gbogbo ni sise.

No comments:

Post a Comment

Pages