Aare Tinubu ni Aare Akoko to je Omo Yoruba--Oloye Salvador - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, July 14, 2023

Aare Tinubu ni Aare Akoko to je Omo Yoruba--Oloye Salvador


Laipe yii ni awon egbe Akoroyin l'ede Yoruba sabewo si Odo agba oje oloselu nipinle Eko nni,iyen Oloye Olagoke Salvador,ti Omo bibi ipinle Eko yii si ti je ko di Mimo pe,Aare Tinubu ni Aare Akoko to je Omo Ile Yoruba atata,o so pe ojulowo Omo Yoruba ponbele ni Aare wa,o salaye siwaju si i pe,Aare ana iyen Oloye Olusegun Obasanjo le je Yoruba loooto sugbon ologun ni.
Oloye Salvador ti tun wa be awon obi ati ijoba lati je kawon ogo weere wa mo pe,ede Yoruba dun l'ede,bee lo Dara lati mu Eko imo yoruba lokukundun kaakiri awon ileewe wa.
Baba yii tun soro nipa ise agbe,pe o dara ki Iran Yoruba mo pe,ise agbe nise Ile wa,Oloye Salvador wa ro gbogbo awon olugbe orile ede yii lati ni suuru fun Aare Tuntun,ati pe idaniloju ti wa gedegbe pe,Omo Olodo ide ni yoo mu wa de Ile ileri.

No comments:

Post a Comment

Pages