Yomi Fabiyi ati Jaiye Kuti gbena woju Ara won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, July 14, 2023

Yomi Fabiyi ati Jaiye Kuti gbena woju Ara won


Nitori Oro ti oseretiata obinrin to n je Jaye Kuti so nipa awon oseretiata to n toro owo Lori ero ayelujara pe,iwa naa ko Dara ati pe o n ko itiju ba egbe onitiata,o tun so pe boya awon oseretiata yii ti Fi ojo aaro won sere ni 
Loju ese ni Yomi Fabiyi to je oseretiata okunrin ti fun Jaye lesi pe,ti ko ba le ran awon oseretiata yii lowo,ko gbe Enu e Dake ko ma tun Dena awon to setan lati ran won lowo ati pe onigberaga ni Jaye
Inu opo awon ololufe fiimu Yoruba ti wa n dun si esi ti Yomi fun Jaye,topo si ti n pe Jaye ni asewo ati pe Oro to so naa ko Dara to

No comments:

Post a Comment

Pages