Api baide tu yuuu oba Orin - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, August 7, 2023

Api baide tu yuuu oba Orin

Gbogbo ojo keje OSU kejo ni ayeye ojo ibi oba Orin,Alaaji Saheed Babatunde Ayinla Okunola Akorede Osupa,gbogbo awon ololufe oba Orin ni won ti ki I ku oriire ojo ibi re,Omo bibi ilu Ibadan to wa ni Orile ede America bayii naa si dupe lowo adaniwaye fun idasi emi re,Alagbede Orin ti wa seleri pe,oun yoo de sorile ede yii laipe kawon ololufe oun maa reti oun,ileese tojubole ati gbogbo iwe iroyin Yoruba lo n ki Jakky pe ,Api baide tu yuuu 

No comments:

Post a Comment

Pages