Ilaji milioonu ni oba Orin Osupa fun baba Bankefa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, August 7, 2023

Ilaji milioonu ni oba Orin Osupa fun baba Bankefa


Oba Orin iyen Alaaji Saheed Osupa ti pada fun agba oje oseretiata nni baba Bankefa n idaji milioonu bayii,ojo ojo ibi oba Orin gan an ni Omo bibi ilu Ibadan naa fun baba Bankefa lowo lati Fi toju Ara e,aisan roparose lo n yo baba yii lenu to si so pe,oun ti pe opo oseretiata lati ran oun lowo sugbon ti pupo ninu won ko dahun
Sa o ,oba Orin Osupa ti pada fun baba Bankefa lowo ti opo awon eeyan si ti n sadura fun oba Orin 

No comments:

Post a Comment

Pages