Odu ni Alaaji Mutairu Owoeye je ti a ba n soro nipa onisowo Ile ati Ile rira,baba yii ti wa tipe ninu ise karakata Ile gbigbe ati Ile,sugbon ose to koja lawon kan so pe baba naa ko awon toogi lo si Abule Adunbun nitosi Ewekoro ,baba yii ti wa salaye pe,oun ko mo ohunkohun nipa ija to sele laarin ilu yii ati pe awon Ota oun lo wa nidi ibaniloruko je naa
Baba Owoeye so pe,o ti le ni ose meji toun ti wa ni Ile iwosan sugbon ti Olorun ti gbakoso,baba so pe oun ko mo nipa ija ti awon toogi lo ba baale Abule Adunbun ja rara ati pe ko dun mo oun ninu bi won se daruko oba olu Itori sinu iroyin eleje naa nitori oba ti ko Fe wahala laarin ilu ni oba Akamo
Baba so pe,oun ti pe akiyesi Olu Itori si ohun to sele yii beeni Gomina ipinle Ogun gan an ti seleri lati pase alaafia saarin ilu naa

No comments:
Post a Comment