Eyin eleyinju aanu ati olufe fiimu yoruba agbelewo,asiko yii ni baba Bankefa to je agba oje oseretiata niilo iranlowo wa,baba salaye ninu fidio to Fi sita pe,oun ti pe awon olorin fuji bii ,Pasuma ati Osupa sugbon ti oun ko ri iranlowo lodo,o so pe Funke Akindele ati Funke Etti gan an ri atejise oun pe oun niilo iranlowo sugbon won ko dahun
Baba yii ti wa n be awon ololufe fiimu atawon eleyinju aanu lati saanu oun nitori aisan roparose ti da a gunle lati odun die seyin

No comments:
Post a Comment