Mo mo nipa ni oloogbe Barrister se Fi Saheed Osupa j'oba fuji--Kola Olotu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, August 15, 2023

Mo mo nipa ni oloogbe Barrister se Fi Saheed Osupa j'oba fuji--Kola Olotu


Agba oje nidi ise sorosoro nni iyen Oloye Kolawole Olotu ti so pe Saheed Osupa ko ranti oun mo ,o salaye pe lati igba to ti joba Fuji ni Omo bibi ilu Ibadan naa ko ti ranti oun rara
O salaye pe,bi Oloogbe Barrister se Fi Olori ebi Olufimo joba Fuji ko seyin oun rara sugbon to je ohun iyalenu pe, Osupa ko ranti oun tabi San oore toun se fun un pada
Loju ese ni Olori ebi Olufimo ti da Oloye Olotu lohun pelu orin'Baba Gebu Koda gele ti oba Orin to sese de lati Orile ede America se bo sile ninu baalu lo ti mu Orin senu lati Fi fun Oloye kola ni esi Oro re.

No comments:

Post a Comment

Pages