Aare Adetola Emmanuel King n ki Oba Yaya ti Nupe nipinle Niger ku oriire ayeye Ogun odun Lori ipo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, September 16, 2023

Aare Adetola Emmanuel King n ki Oba Yaya ti Nupe nipinle Niger ku oriire ayeye Ogun odun Lori ipo

Aare Adetola Emmanuel King iyen oludasile ileese Adrons Home and properties n ki oba Yaya Abubakar ku oriire ayeye Ogun odun Lori ipo gege bii Etsu Nupe nipinle Niger,beeni baba alaanu awon mekunnu yii n sadura pe,emi Oba Yaya yoo sopo odun Lori ipo naa,Ooni Ile ife naa wa nibi ayeye to waye nipinle Niger lojo satide yii
Aare Adetola tun wa n Fi asiko yii so fun eyin olugbe Orile ede yii pe, Ile gbigbe di irorun pelu ileese Adrons,ati pe aye wa lati sanwo diedie ki e le di onile Lori,e le kan si ileese Adrons to ba wa nitosi yin fun alaye lekunrere

No comments:

Post a Comment

Pages