Eleyele so pe Ika lopo awon puromota yii to si je pe ki won maa ko ibasun fun awon obinrin nikan ni won mo
Baba Itunu naa ti wa fun Busola Oke lesi oro e o,o so pe oun ko je Busola ni owo kankan ati pe oun ko kenu ife si I ri sugbon idi ti Busola Fi wa n ba oun loruko je leyin opo odun tawon ti Jo sise papo ni ko ye oun rara
Ibi ti Oro awon mejeeji yii yoo yori si ni enikeni ko le so sugbon epe rabanderabande lawon mejeeji n gbe Ara won se Lori ero ayelujara lasiko yii
No comments:
Post a Comment