E ma pe mi ni Alaaja mo o--Lizzy Anjorin - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, September 1, 2023

E ma pe mi ni Alaaja mo o--Lizzy Anjorin


Lizzy Anjorin so pe,nitori awon musulumi ki n gbeja oun lasiko tawon kan ba n bu oun Lori ero ayelujara,idi ni yii ti oun ko se Fe kawon eeyan maa pe oun ni Alaaja mo

No comments:

Post a Comment

Pages