Ti a ba n soro nipa ileese to se e gbe Okan le nipa Ile tita lowo pooku,asiwaju ni ileese Adrons Home and properties je,ofiisi won wa kaakiri Orile ede yii,beeni aye wa lati sanwo diedie fun irorun eyin onibaara won
Laipe yii ni oludari ileese Adrons olola julo,Aare Emmanuelking Adetola so pe,Inu oun yoo dun ki gbogbo awon eeyan di onile Lori eyi lo mu u so pe,edinwo ti wa fawon Ile won kaakiri titi to Fi de oke oya.
Bee lo so pe,e le maa sanwo diedie titi Ile naa yoo Fi di ti yin,boya eyin feran lati ba ileese alalubarika yii dowo Po,e kan si Okan ninu awon ileese won to ba wa lagbegbe yin.Ileese Adrons:;;ile gbigbe dirorun pelu won
No comments:
Post a Comment