Won ko ni gba oniroyin laaye lasiko 'Eto'fun Olori omooba Akile ijebu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, September 12, 2023

Won ko ni gba oniroyin laaye lasiko 'Eto'fun Olori omooba Akile ijebu


Ojo kejidinlogun OSU kesan an yii ni ayeye 'eto' fun Olori omooba Akile ijebu lapapo yoo bere,Alaaji Wasiu Ayinde ni Awujale gbe si ipo naa laipe ti ayeye ti yoo waye fun opo ojo yii yoo bere laipe
Gege bi a se gbo pe,ko si aye fawon oniroyin lasiko ti 'eto' ba n lo lowo sugbon ojo weje-wemu nikan ni awon oniroyin ni anfaani lati wa nibe

No comments:

Post a Comment

Pages