Ki nse iroyin mo pe fidio ibi ti won ti n Laago idi arewa oseretiata obinrin nni iyen Moyo Lawal ti wa kaakiri Ori ero ayelujara,sugbon tawon kan ti n so pe, Moyo mo nipa fidio naa nitori oun ati ololufe e n woju ero ayaworan lasiko ti won n se 'kini yen lowo
Awon kan ni Moyo Fe Fi wa onibara si I ni sugbon tawon kan n so pe okunrin yen ni eeyan ibi to tase Moyo sita nitori o fariga pe oun ko Fe okunrin naa mo
No comments:
Post a Comment