Oludasile Ileese Adrons Home,Ololajulo Aare Emmanuelking Adetola ti ri isoro topo eeyan n koju nipa ainilelori eyi lo mu ogbontarigi onisowo Ile tita nni s'eto Ile sawon oke oya bii, Sokoto,Kebbi,Kano atawon ibomin in ,Koda anfaani lati maa dawo diedie laarin odun kan wa titi ti owo naa yoo Fi pe ki onitohun si di lanloodu ara e laarin ojo perente
Aare Adetola to je Omo bibi ipinle Ogun yii so pe awon olugbe ipinle Eko naa ni anfaani lati di Onile nitori awon Ile to Dara wa ni Epe, Sagamu,Shimawa ,Lekki atawon ibomiran fun tita fawon mekunnu lowo pooku
O salaye pe,oun fe ki opo awon eeyan mo asiko isejoba Tuntun labe Aare Tinubu si daadaa ati pe ki Ile gbigbe le rorun fawon olugbe Orile ede yii ni,ti e ba Fe mo si I nipa ileese to n saanu awon ololufe e lati di onile Lori e kan si ileese Adrons to wa kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment