Nitori bi awon Odo se n Fi ehonu han kaakiri agbaye Lori iru iku to seni ni kayeefi to pa odomode olorin takasufe to n je Imole Aloba Mohbad lo mu Iko Olopaa ipinle Eko pase pe ki won lo wu oku e leyin ose kan ti won ti sin in
Won se eyi lati le se ayewo iru iku to pa Okan ninu awon ogo ojo ola Orile ede yii, orisirisi awuyewuye lo ti n lo nigboro nipa iku Mohbad sugbon ti Oga Olopaa ipinle Eko,Owohunwa ti sele lati foro wa awon to ye ati to to wo lenu beeni won yoo se ayewo iru iku to pa Oloogbe ki won to sin in pada gege bii ibeere awon ololufe Mohbad .
No comments:
Post a Comment