Inu idunnu ni idile Oloye Shile Alexander wa lasiko yii pelu bi onisowo Ile tita naa se bi ibeji lose to koja,ti ayeye ikomojade si waye ni ojo toside iyen ojo ojobo ose yii
Awon ololufe Oloye Shile ba a dupe lowo Olorun fun Ebun lantilanti naa
NIPA IROYIN TOJUBOLE
No comments:
Post a Comment