Oni ni ojo ibi ,Oloye Lajero ,ore timotimo oba Orin Osupa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, September 24, 2023

Oni ni ojo ibi ,Oloye Lajero ,ore timotimo oba Orin Osupa


Gbogbo ojo kerinlelogun osu kesan an ni ayajo ojo ibi Oloye Lajero onisowo irin-ikole ni Apapa ipinle Eko
Okan ninu awon ololufe oba Orin iyen Alaaji Saheed Osupa ni Oloye Lajero to je okan ninu agba egbe' Osupa Royal parliament 'adura ti wa ni pe,emi re a sopo odun laye ninu alaafia ati owo to Po repete,api baide tu yuuu 'Lajero '

No comments:

Post a Comment

Pages