Ope o! Obinrin onilu Ara,Aralola di Gomina egbe PMAN ipinle Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, September 23, 2023

Ope o! Obinrin onilu Ara,Aralola di Gomina egbe PMAN ipinle Eko


Gbogbo awon ololufe obinrin onilu Ara iyen Aralola ni won ti n ki I ku oriire ti yiyan sipo e gege bii Gomina egbe PMAN nipinle Eko.Serifatu Olamuyiwa ti gbogbo eeyan mo si Ara ni Gomina fun egbe awon olorin iyen PMAN nipinle Eko bayii
Ose to koja ni Aare egbe naa,Pretty Okafor fowo si yiyan sipo Arewa obinrin olopolo pipe naa gege bii asiwaju awon olorin ipinle Eko,oun ni yoo maa tuko egbe yii nipinle Eko titi digbati won yoo Fi dibo Yan awon Oloye Tuntun
Omo bibi ilu Ondo ni Aralola,to si ti kopa pupo fun idagbasoke ati ilosiwaju ariya lorile ede yii ati loke Okun.Awon ololufe gbajumo ati Arewa obinrin onilu Ara yii si ti n ki i ku oriire.

No comments:

Post a Comment

Pages