Aragbiji ti Iragbiji oba Rasheed Olabomi ti dupe lowo oludasile ileese Adrons Home Ololajulo Aare Emmanuelking Adetola fun idagbasoke ti Omo bibi ipinle Ogun naa mu ba ilu Iragbiji lapapo
Kabiesi soro yii lasiko ti ileese Adrons sabewo silu naa,a gbo pe Inu oba Alade yii dun gidi nitori ipolowo ti ileese Adrons n se fawon onibara e pe,Ile fun Ile gbigbe ati ise agbe wa ni tita lowo pooku,ti eyi yoo si mu idagbasoke ba ilu Iragbiji
No comments:
Post a Comment