Api baide tuu yuuu,Lateef Okunola Libra - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, October 1, 2023

Api baide tuu yuuu,Lateef Okunola Libra

Gbogbo ojo kinni osu kewa ni ayeye ayajo ojo ibi Oloye Adeola Lateef Okunola topo eeyan mo si Lattylibra,odu ni Lattylibra laarin awon puromota Orin Fuji, Ogbeni yii to je egbon oba Orin Osupa Babatunde lo n sojo ibi loni in,adura tiwa ni pe ki emi Lattylibra se opo odun laye ninu alaafia ati owo pelu ilera pipe

No comments:

Post a Comment

Pages