Aare egbe OpC Reformed iyen Komureedi Dare Adesope ti so lose to koja lasiko to ba awon egbe Akoroyin l'ede oyinbo soro lasiko iforowero to waye pe,o je ohun amoriya pe,Aare Tinubu yan pupo ninu awon Omo Yoruba sawon ipo to dara ninu eto isejoba re
Komureedi Adesope to je akowe agba fun Oloogbe Oloye Fasehun lasiko kan tun so pe,odun 2016 ni won sefilole egbe OPC reformed ti Alaafin ana iku baba Yeye oba Adeyemi si gbe opa ase fun won ti eyi je igba Akoko ti oba Alade maa gbe opa ase le Aare ninu egbe OPC reformed,bee lo so pe baba Yemi Elebuibon to je Araba tilu Oshogbo naa wa nikale lojo naa
Komureedi ko sa I menuba iwa ti Aare Ana lorile ede yii Oloye Obasanjo wu sawon oba lose die seyin nipinle Oyo,o salaye pe toun ba wa nibe lojo naa ni ohun to sele yii ko ni i sele o salaye pe iwa ti Oloye Obasanjo wu yii ku die kaato nipa pipase fawon Ori Ade sugbon eyi ko le Salai ma waye nigba to je pe,ijoba lo n Yan oba bee lo je pe,awon naa ni won n sanwo osu fawon oba yii.
Komureedi Adesope ti wa so pe,oun ati Aare ona kakanfo Ile Yoruba iyen iba Gani ki n se Ota o,ati pe opo igba lawon ti pade lode ariya o kan je pe egbe otooto lawon n se ninu egbe OPC ni
No comments:
Post a Comment