Olori omooba Akile ijebu lapapo,Alaaji Wasiu Ayinde Olasunkanmi Adesanya Marshal sedaro , Otunba fidipote Akile Ijebu iyen Otunba Wahab Akanmu Osinusi to dagbere Faye lojo satide to koja lo yii
Oluaye fawon onifuji to tun je Olori omooba Akile ijebu lapapo Alaaji Wasiu Ayinde sapejuwe Oloogbe Osinusi gege bii eeyan gidi,to feran tomode tagba denu,Mayegun Ile Yoruba lapapo so pe,ibanuje nla ni iku Otunba fidipote Akile ijebu je foun nitori ipa ti Oloogbe ko lasiko oye Tuntun ti oun sese je lodo Awujale oba Sikiru Adetona ki n se kekere rara sugbon to je ohun ibanuje pe, Otunba Wahab Osinusi ku leyin ojo die ti oun joye Olori omooba Akile ijebu lapapo
''Omo oba Jadiara/fidipote,Omo Alakatapo to se bi obo o gbon ,obo gbon tinu obo lobo n se''sun un re o Alaaji Wasiu Ayinde Adesanya Marshal lo sedaro re.
No comments:
Post a Comment