Gbogbo awon to wa nibi odun olojo to waye ni Ile ife lose to koja ni won ti n gbe osuba sadankata fun Ileese Adrons iyen ileese to n ta Ile lowo pooku fawon onibara e,Inu Ooni Ile ife oba Enitan gan an dun fun ohun ti ileese Adrons se yii
Fun gbogbo eyin ti e Fe ba wa fowo Po nileese wa,e kan si Okan ninu awon ofiisi wa lagbegbe yin
No comments:
Post a Comment