Aare Adetola to je Oludasile Ileese Adrons Home and properties ti Fi asiko yii ki gbogbo awon Omo Orile ede yii ku oriire ayeye odun metalelogota ti a gba ominira,bee lo so pe Ile wa ni tita lowo pooku kaakiri Orile ede yii,Ebun jije wa fawon onibara won pelu.E le kan si Okan ninu awon ofiisi Adrons to wa lagbegbe yin'Ileese Adrons,Ona irorun lati di onile loti'
Saturday, October 7, 2023

Ileese Adrons ki awon olugbe Orile ede yii ku ayeye odun metalelogota
Aare Adetola to je Oludasile Ileese Adrons Home and properties ti Fi asiko yii ki gbogbo awon Omo Orile ede yii ku oriire ayeye odun metalelogota ti a gba ominira,bee lo so pe Ile wa ni tita lowo pooku kaakiri Orile ede yii,Ebun jije wa fawon onibara won pelu.E le kan si Okan ninu awon ofiisi Adrons to wa lagbegbe yin'Ileese Adrons,Ona irorun lati di onile loti'
Ẹka Iroyin
# Iroyin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Iroyin
Labels:
Iroyin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment