Ojo kefa osu kewa odun yii ni Gomina ipinle Eko Ogbeni Sanwo olu je ko ye awon olugbe ipinle Eko ati Orile ede yii lapapo pe,ileese Adrons Home and properties nikan nileese to se e gbojule nibi karakata Ile pelu ifokanbale
Ibi ayeye kan to waye nibi tawon laamilaaka atawon borokini eeyan wa ni Gomina ti soro yii ,o je ko di mimo pe,ilu Epe nipinle Eko ti di ilu Oyinbo lasiko yii nitori awon ohun meremere to wa nilu naa,yato si ileese Dangote to wa nibe opo awon ohun amayederun lo wa ni agbegbe yii to si je wipe ijoba ipinle Eko gan an fowo si i pe,ileese Adrons lo se e gbojule ti enikeni ba Fe e ra Ile si ilu Epe ati agbegbe re
Boya eyin Fe mo si i nipa ileese to n ta Ile nirorun fawon onibara re,e le kan si ileese Adrons to wa nitosi yin nitori ileese yii nikan lo se e gbojule ta ba n soro nipa Ile ati ibugbe rira
No comments:
Post a Comment