Iroyin Ayo to tun gba igboro lasiko yii ni pe, olufimo akoko iyen Alaaji Saheed Osupa ti ni Arole nidi ise Fuji,Riliwan Isola loruko okunrin to n korin bii oba Orin Osupa yii n je ilu Ibadan lo n gbe sugbon ko si ibi ti e ti pe e sode ere ti ko ni i ti wa fi Orin Fuji to dangajia da a yin laraya,e le pe arole Olufimo sori nomba yii,07034767859
Sunday, October 15, 2023
Ishola Rilwan re e o,Arole Olufimo to n korin bii Saheed Osupa
Iroyin Ayo to tun gba igboro lasiko yii ni pe, olufimo akoko iyen Alaaji Saheed Osupa ti ni Arole nidi ise Fuji,Riliwan Isola loruko okunrin to n korin bii oba Orin Osupa yii n je ilu Ibadan lo n gbe sugbon ko si ibi ti e ti pe e sode ere ti ko ni i ti wa fi Orin Fuji to dangajia da a yin laraya,e le pe arole Olufimo sori nomba yii,07034767859
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment