Tani Olohun ti be awon musulumi ilorin o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, October 15, 2023

Tani Olohun ti be awon musulumi ilorin o


Leta ti Ogbeni Adegbola Asiisi iyen Tani Olohun ko nipase loya re sawon musulumi ilorin re e o,nibe lo ti rawo ebe sawon musulumi ilorin paapaa awon Ogo ilorin lapapo to si ti so pe,iru iwa yii ko ni i waye latowo oun mo
Ki n se iroyin mo pe,awon Ogo ilorin labe Alaaji Muritala Kareem gbe Ogbeni Adegbola pelu esun pe ,o n soro ti ko dara nipa awon musulumi ati iwe Mimo kuraani,ti awon egbe musulumi ilorin si lo gba ase latodo awon Iko Olopaa lati gbe Ogbeni yii sugbon ni bayii Ogbeni Tani Olohun ti rawo ebe sawon egbe musulumi ilorin ti awon naa si ti gba ebe re labe ase latodo, Alaaji Muritala Kareem baba n bariga,Aafa Ahmad Lagbaji ati Aafa Baba Tonile Okuta Agidi.

No comments:

Post a Comment

Pages