Oluomo Kotonu lo n sojo ibi loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, October 9, 2023

Oluomo Kotonu lo n sojo ibi loni in


Gbogbo ojo kewa osu kewa layeye ojo ibi Alaaji Saheed Babatunde iyen Oluomo Kutonu, ololufe awon oniroyin ni Omo bibi ipinle Osun yii,baba alaanu mekunnu ni opo mo Oluomo Kutonu si,adura ti wa ni pe emi Oluomo Kutonu yoo sopo odun laye ninu alaafia,owo ati aisiki pupo,api baide tu yuuu Oluomo Kutonu 

No comments:

Post a Comment

Pages