Onijita ati aluduru Wasiu Ayinde salo mo o lowo ni London - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, October 9, 2023

Onijita ati aluduru Wasiu Ayinde salo mo o lowo ni London


Pupo ninu awon to gbo pe,omoose Oluaye Fuji iyen Alaaji Wasiu Ayinde meji ti Japa mo o lowo ni Orile ede London lasiko ti won lo sere nibe ni won ti n so pe,iwa ti ko Dara lawon omoose re mejeeji na Wu sugbon tawon kan ti n so pe ko si ohun to buru nibe

No comments:

Post a Comment

Pages