Iroyin ayọ re e fawọn onibara ileeṣẹ Adrons home and properties iyen ileese to n ta ile lona irorun fawon olugbe orile ede yii.
Pelu ogota taosan
(60 k) ẹbun bii irẹsi,ẹrọ ilọta,faanu,ẹrọ idana lo jẹ ẹbun ti ẹ maa gbe lọ si ile iyẹn ti e ba da owo to to ogota taosan lati fi saami pe e setan lati ra ile lodo won.Pelu #100 taosan e maa je ebun bii,iresi,ororo,gaasi idana,adie nigbati awon to ba san #200 taosan ninu owo ile ti won fe e ra nileese Adrons yoo je ebun bii eran agbo,iresi,abẹbẹ ifẹrun,faanu.
Pelu milioonu kan ebun bii amohunmaworan,eran agbo,apo iresi,ero amule tutu le o je nileese Adrons
Pelu milioonu kan abo naira,ebun amohunmaworan,eran agbo,firiigi lo wa nile fun yin nigbati awon to koko san milioonu meji yoo jebun bii,firisa,firiiji,iresi apo atawon ebun nla miran
E kan si ileese Adrons to ba sunmo o yin lati je anfaani awon ebun yii nipa rira ile ti ko ni wahala lori lowo won.Adrons irorun ile gbigbe lo je wa logun

No comments:
Post a Comment