Nitori baba olowo oga onimoto ni awon akeegbe Segun Ogungbe ko se e tele e lo sibi oku iya Wunmi o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, November 19, 2023

Nitori baba olowo oga onimoto ni awon akeegbe Segun Ogungbe ko se e tele e lo sibi oku iya Wunmi o


O yẹ kawọn akẹgbẹẹ Ṣegun Ogungbe tele e lo sibi oku iya Wunmi Ajiboye iyen iyawo e keji tele,sugbon awon bii Odunlade Adekola,Owolabi Ajasa ko lati tele e nitori ikoko obe won(oga onimoto) iyen baba olowo ti Wunmi n tele kiri lasiko yii
Ekunrere iroyin n bo laipe.

No comments:

Post a Comment

Pages