Olowo ti gba iyawo Ṣegun Ogungbe o,o maṣe o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, November 19, 2023

Olowo ti gba iyawo Ṣegun Ogungbe o,o maṣe o


Wọn n sọ kiri igboro pe,ọga onimọto kan lo pe Oluaye iyen Alaaji Wasiu Ayinde ko wa sere nibi oku iya Wunmi Ajiboye oseretiata yoruba nilu Oshogbo,a tun gbo pe nitori oga awon onimoto yii ni Wunmi se ko Segun Ogungbe oko e sile,lawon eeyan ba n bu Segun pe ,ori Tinuke iyawo e akoko lo mu u
Tani oga onimoto yii gan an?oga awon onimoto to n la gbogbo awon oseretiata obinrin wa,gbogbo won lo ti ba sere ipa ni kooro yaara tan,a fi suuru o.

No comments:

Post a Comment

Pages