Igba ọtun ti de fawọn onibara ileeṣẹ Adons iyẹn ileeṣẹ to n ta ilẹ lowo pọọku kaakiri orilẹ ede yii paapaa lasiko odun keresi ati odun tuntun to n bo yii
Won tun maa n ba awon onibara won se iwe ile ati ile beeni aye lati san owo ile ti e fe ra lodo won diedie nitori irorun awon olugbe orile ede yii lo je won logun
Ebun odun bii eran maalu,iresi,ororo atawon ohun ti yoo wulo fun yin ti wa nile nileese Adrons fun igbadun eyin ololufe won,e ma gbagbe pe,ko si ibi ti owoja ileese Adrons ko de kaakiri Orile ede yii,boya eyin fe bawon ra ile tabi dukia e tete kan si ileese Adrons to ba wa nitosi yin.Adrons.....ona irorun lati di onile lori.

No comments:
Post a Comment