Iyawo Oludari ileeṣẹ Adrons ,Olori Aderonkẹ Emmanuelking lo dari eto ti ileeṣẹ Adrons home and properties sagbekale e losu kẹwa ọdun yii,gbogbo oṣu kẹwa ni ayajọ ọjọ idanilẹkọ nipa aisan jẹjẹrẹ ọmu
Olori Aderonkẹ ti wa be awọn obinrin lati ma a ṣayẹwo ọmu wọn loorekoore bẹẹni ki wọn tete lọ si ileewosan ti wọn ba ṣakiyesi ohunkohun ninu ọmu
wọn ati pe,iṣẹ aṣeju,ironu ati aijẹ eso le tete fa aisan jẹjẹrẹ ọmu
No comments:
Post a Comment