ọjọ kẹsan ọṣu kejila ni ilu Arigbajo Ifọ ipinlẹ Ogun yoo mi titi nibi ọdun ifa oloye Ifayọmi Babatunde,Ọba Orin Osupa ati Tọpẹ Nautical ni yoo sere fawon ololufe ifa lati ojo keje si ojo kesan an ni ayeye yii yoo fi waye,eleekesan iru e niyi nilu Arigbajo ifo,gbogbo eyin ololufe ifa ni obaedu pe sibi odun ifa ti odun yii boya eyin fe mo nipa ayeye odunifa yii tabi e fe beere nipa igbesi aye yin e pe,08020587706
Thursday, November 30, 2023
Oṣupa yoo dalubolẹ nibi ọdun ifa ỌbaEdu
ọjọ kẹsan ọṣu kejila ni ilu Arigbajo Ifọ ipinlẹ Ogun yoo mi titi nibi ọdun ifa oloye Ifayọmi Babatunde,Ọba Orin Osupa ati Tọpẹ Nautical ni yoo sere fawon ololufe ifa lati ojo keje si ojo kesan an ni ayeye yii yoo fi waye,eleekesan iru e niyi nilu Arigbajo ifo,gbogbo eyin ololufe ifa ni obaedu pe sibi odun ifa ti odun yii boya eyin fe mo nipa ayeye odunifa yii tabi e fe beere nipa igbesi aye yin e pe,08020587706
Ẹka Iroyin
# Esin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Esin
Labels:
Esin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment