Inu gbogbo awon oniroyin to le ni igba dun lọ si ile wọn lọjọ sannde to lọ yii lasiko ti Aarẹ Adetọla Emmanuelking to je oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e gbọkanle ninu ọrọ ilẹ tita lorilẹ ede Naijiria,ẹbun bii foonu,laputọọpu ati ọkọ ayọkẹlẹ ni awọn oniroyin yii jẹ lẹyin ti gbogbo wọn gba irẹsi apo kọọkan,adiẹ meji meji ati ororo galọọnu kọọkan lọ sile
Aare Adetọla ti wa tun sọ pe,ẹdinwo wa lori ilẹ tawọn oniroyin ba ra nileeṣẹ ADRONS o,bẹẹ lo fi idunnu rẹ han fun iṣẹ takuntakun ti wọn n ṣe.

No comments:
Post a Comment