Kolabo to mu ọgbọn dani lati ẹnu baba oko ati Ere asalatu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, December 20, 2023

Kolabo to mu ọgbọn dani lati ẹnu baba oko ati Ere asalatu


Gbogbo ẹyin ololufẹ fuji ati orin musulumi la n ki ku ojulọna orin ọlọpọlọ pipe latẹnu ọmọ oko to ti di baba oko ninu iṣẹ orin fuji kikọ ,Alaaji Ṣẹfiu Adekunle Alao ati Alaaji Bukọla Ere  Asalatu,fun igbadun ẹyin ololufẹ orin fuji atorin musulumi,orin naa yoo jade laipẹ ti yoo si migboro titi.E ku ojulọna

No comments:

Post a Comment

Pages