Aarẹ Emmanuelking ṣọdun fawọn osiṣẹ re - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, December 26, 2023

Aarẹ Emmanuelking ṣọdun fawọn osiṣẹ re


oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS,Aarẹ Emmanuelking ti fi ẹrin sẹẹkẹ awọn oṣiṣẹ rẹ nipa fifun wọn lẹbun ọdun ati ami ẹyẹ.pẹlu idunnu ni gbogbo awọn oṣiṣẹ yii fi dupẹ lọwọ oludasilẹ ileeṣẹ wọn,ẹ ma gbagbe pe Aarẹ fawọn oniroyin to le ni igba lẹbun ọdun lọsẹ diẹ sẹyin ti ọpọ tun gba ọkọ ayọkẹlẹ,irẹsi,ororo ,adiẹ lọ sile pẹlu

No comments:

Post a Comment

Pages