ọjọ kẹsan an oṣu kejila yii ni apapọ ẹgbẹ to n ta ilẹ ati ile ni Orile ede yii ẹka ti ipinlẹ Eko iyẹn REDAN fun ileese ADRONS lami ẹyẹ gẹgẹ bii ileeṣẹ to peregede julọ nipa ilẹ tita,THE GRAND AFRICAN BALLROOM LAGOS CONTINENTAL HOTEL,ni Kofo Abayọmi nipinlẹ Eko ni ayẹyẹ naa ti waye,tẹ o ba gbagbe pe ileeṣẹ ADRONS tun gbami ẹyẹ lọjọ kọkandinlogun oṣu yii bakanna,ti wọn si fi ami ẹyẹ yii sọri awọn onibara wọn,boya ẹyin n wa ileeṣẹ to ṣe e fọkantan nipa ilẹ rira,ẹ tete lọ si ọfiisi ADRONS to ba wa ladugbo yin.
Tuesday, December 26, 2023
REDAN fun ileeṣẹ ADRONS ni ami ẹyẹ
ọjọ kẹsan an oṣu kejila yii ni apapọ ẹgbẹ to n ta ilẹ ati ile ni Orile ede yii ẹka ti ipinlẹ Eko iyẹn REDAN fun ileese ADRONS lami ẹyẹ gẹgẹ bii ileeṣẹ to peregede julọ nipa ilẹ tita,THE GRAND AFRICAN BALLROOM LAGOS CONTINENTAL HOTEL,ni Kofo Abayọmi nipinlẹ Eko ni ayẹyẹ naa ti waye,tẹ o ba gbagbe pe ileeṣẹ ADRONS tun gbami ẹyẹ lọjọ kọkandinlogun oṣu yii bakanna,ti wọn si fi ami ẹyẹ yii sọri awọn onibara wọn,boya ẹyin n wa ileeṣẹ to ṣe e fọkantan nipa ilẹ rira,ẹ tete lọ si ọfiisi ADRONS to ba wa ladugbo yin.
Ẹka Iroyin
# Iroyin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Iroyin
Labels:
Iroyin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment