Kiyesi,ma beru lati di onile lori--Ileeṣẹ ADRONS - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, December 5, 2023

Kiyesi,ma beru lati di onile lori--Ileeṣẹ ADRONS


Ọpọ igba ni wahala awọn ọmọ onilẹ maa n dẹruba awọn to fẹ ra ilẹ ati oriṣiriṣi idaamu lẹyin ti ẹ ba ra ilẹ naa tan ṣugbọn iroyin ayọ to wa nigboro lasiko yii ni pe,ileeṣẹ alalubarika iyẹn ADRONS homes and property ti de lati fopin sawon isoro yii
Aye wa lati maa sanwo diedie,ileese Adrons ni ile si origun mereerin orile ede yii,Abuja,Ijebu ode,Sagamu,Eko,Ibeju,Niger,Nasarawa,Jos,Papalanto,Atan ota,Epe,Ado Ekiti,Ibadan.
Ilẹ lati fi ṣe iṣẹ agbẹ tabi sin ohun ọsin wa pẹlu beeni ko si wahala ọmọ onilẹ rara.
Ẹ le kan si ofiisi wọn to ba sunmọ yin tabi ki ẹ ba wọn sọrọ lori ẹrọ ayelujara.pẹlu ileeṣẹ ADRONS irọrun ni lati di onile lori

No comments:

Post a Comment

Pages