Okiki Bright ati Yeye Dara yoo dalubole ni orile ede London loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, December 24, 2023

Okiki Bright ati Yeye Dara yoo dalubole ni orile ede London loni in


Gbogbo eto lo ti to fawon ololufe olorin ti okiki re n kan kiri lasiko yii iyen Okiki Bright pelu bo se maa da awon ololufe e laraya loni ojo satide ni orileede naa,boya eyin fe pe okiki si ode ere to ba pada de si orile ede yii e le pe nomba re,08082024957 ẹ ma gbagbe pe ati orin juju ,fuji,highlife ni Okiki Bright nko fun igbadun eyin ololufe e

No comments:

Post a Comment

Pages